Shola Allyson – Asise Osi | Download Mp3
Shola Allyson - Asise Osi
Shola Allyson – Asise Osi is right here on Zummy for Downloads.
After completing the project, Imisi by Shola Allyson, a fascinating record called Asise Osi was released. It tells the story of a woman struggling to find her place in the world and her relationships with others. It is an interesting and powerful record that is sure to appeal to fans of Shola Allyson’s previous work.
Shola Allyson, a talented Nigerian gospel singer, has released a new album called Asise Osi. The album is full of beautiful songs that are guaranteed to make everyone smile. Shola has worked hard to create this amazing album, and we’re sure you’ll love it!
Asise Osi is the fourth track on the album, and Sola Allyson-Obaniyi is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter. She is well known for her work with the legendary group, The Fugees.
Listen and share your thoughts below!
SEE VIDEO BELOW: Shola Allyson – Asise Osi
LYRICS: Shola Allyson – Asise Osi
Ibere Po lokan mi
Sugbon Momo poluwa dara
Irin ti mo ri ojin gan
Sibe Sibe mo mo poluwa dara
Awon Ibere Yi wa nko
Idahun yen Nibo nati wa
[irp]
Olutoni farahan mi o
Lori Ibere to wa lokan mi
Ibere Po lokan mi
Sugbon Momo poluwa dara
Irin ti mo ri ojin gan
Sibe sibe mo mo poluwa dara
Awon Ibere Yi wa nko
Idahun yen Nibo nati wa
Olutoni farahan mi o
Lori Ibere to wa lokan mi
Sugbon mo mo asise osi loro re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
Igbamiran gbogbo re ati sunni
Sibe ninu e momo poluwa dara
Ibi ti mo nlo osi jin gan ni
Itoni ni mobere ajo ko san mi o
Awon Ibere Yi wa nko
Idahun yen Nibo nati wa
Olutoni farahan mi o
Lori Ibere to wa lokan mi
Sugbon mo mo asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
Itura a de o Iranwo a wa
Moni ireti Asise osi o
Itura a de o Iranwo a wa
Moni ireti Asise osi o
Itura a de o Iranwo a wa
Moni ireti Asise osi o
Itura a de o Iranwo a wa
Moni ireti Asise osi o
Sibe sibe mo mon asise osi
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
[irp]
Asise osi leto re
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
asise osi loro re
Asise osi leto re
Asise osi loro re
Asise osi leto re
Do you find Zummy useful? Click here to give us five stars rating!