Tope Alabi – Funmilayo | Download Mp3

Tope Alabi – Funmilayo

Check out Tope Alabi – Funmilayo mp3 download

Tope Alabi, a celebrated Nigerian worship minister and Yoruba language songstress, has released a new single titled “Funmilayo.” The song is a soaring affirmation of love and devotion, and is sure to touch the hearts of listeners everywhere.

Released in 2013, this song was the lead single from Agbara Olorun, her seventh album. It tells the story of a young woman who is struggling with her love life and her relationship with her mother. The song is sung in Yoruba, a language spoken in West Africa.

This song has been a massive hit since its release and it deserves to be on your playlist. It has a catchy tune and is easy to listen to. It will get you moving and make you feel happy.

Listen and share your thoughts below!

SEE VIDEO BELOW: Tope Alabi – Funmilayo

LYRICS: Tope Alabi – Funmilayo

Olorun lo le fun ni layo
Eniyan ole funi layo kope
Bo pe titi oo akololo a pe baba
Oba oke lo layo pupo lodo
Funmilayo
Funmilayo
Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Olorun lo le fun ni layo
Eniyan ole funi layo kope

ALSO CHECK  Joe Praize - Unlimited | DOWNLOAD MP3, LYRICS

Bo pe titi oo akololo a pe baba
Oba oke lo layo pupo lodo
Funmilayo
Funmilayo
Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Bi emi basi wa laye ireti o pin oo
Atoro ohun gbogbo lowo olorun ki kan ju o
Oro olorun ko ni lo laiye se laye
Bi omo kiniun wonma kigbe ebi kikan
Awon to gbekele ki yo shale yi ri ohun ti o dara
Olorun lo le fun ni layo
Eniyan ole funi layo kope
Bo pe titi oo akololo a pe baba
Oba oke lo layo pupo lodo
Funmilayo
Funmilayo
Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Bi igba ban gba ni ejiki ama ro ju
Igba nbo ti o gba ni olorun lo ni dede
Ironu o da nkan
Ore lo ni suuru
Eti olorun ko wu wo lati gbo igbe wa
Igba gbo ninu Jesu lo le mu ni se ase yege
Olorun lo le fun ni layo
Eniyan ole funi layo kope
Bo pe titi oo akololo a pe baba
Oba oke lo layo pupo lodo
Funmilayo
Funmilayo
Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Gbe okan le jesu apata ti kin ye
Matori a ro pin ko se si eleda re
Pada leyin aiye ni se ni won to ni pa
Aiye a funi ni fila a fi gba odindin ori eni l’owo eni
Won ti mi a si regun ko ni wu won de ti gbe san
Olorun lo le fun ni layo
Eniyan ole funi layo kope
Bo pe titi oo akololo a pe baba
Oba oke lo layo pupo lodo
Funmilayo
Funmilayo
Funmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Ori to mi a da de ko ma ni se a i de
Funnnnnmilayo
Baba fun mi layo ma je ki temi o gbe oo
Funnnnnmilayo
Ohun to ye mi o baba ma fi dunmi o baba rere amin
Funnnnnmilayo
Oro ti mo ba araye wi to ya gere ba mi se baba
Funnnnnmilayo
Mo mope omo to mi a gun eseee re a tirin
Funnnnnmilayo
Gbogbo a sise jeje eleri e je kalo mu suuru
A fe re bo na
Funnnnnmilayo

ALSO CHECK  Shola Allyson - Asise Osi | Download Mp3

T’ori koko to mi a j’ata idi re a koko gbona, uh uh uh
Funnnnnmilayo
E je ka se fun olorun loke loke l’owo a fun ni gbe eyen je oto
Funnnnnmilayo
Ohun ti afe gba l’owo olorun oju ohun ti a le fun lo eh eh
Funnnnnmilayo
Eni ba fe jeun gboingboin ati eleku gboingboin, tooto niyen
Funnnnnmilayo

 

Do you find ZUMMY useful? Click here to give us five stars rating!

You May Like

error: